Skip to main content

Ojúewé Àkọ́kọ́ Ètò ìtọ́sọ́nàWAPWikispeciesWikinewsWikimedia CommonsMeta-Wiki

Wikipedia pages protected against vandalismWikipedia protected pages without expiry


ÌlànàÀwọn Ìbéèrè Wíwọ́pọ̀ÀgbàjọÀwọn ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ WikipediaỌrẹIbi Ìṣojú (Embassy)ÌbápàdéNew York Cityìtẹ̀síwájú...Che GuevaraCape VerdeÀìṣojúṣájúÌlànà àyọkà kíkọẸ̀tọ́àwòkọÌwà títọ́Ìṣeéyẹ̀wòÌlànà fún kíkọ lẹ́tà YorùbáKíni Wikipedia jẹ́?Àtúnṣe ojúewéÀfikún àwòránÌkópaTutorialÀpótí ìdánwòÀwọn ojúewé tuntunÀwọn àyọkà ọ̀wọ́nÀwọn ojúewé fún ìyílédèdàÀwọn àyọkà fún àtúnṣeÌṣọrẹAbẹ́ igiÀwọn oníṣe WikipediaÀwọn alámùójútóWikimediaSoftwareÀwọn statístíkìWikipediaLítíréṣọ̀Eré-ìdárayáFílmùOrinTíátàÌṣeròyìnTẹlifísànRédíòIṣẹ́ẹ̀rọInternetÀfigbébánisọ̀rọ̀Kọ̀mpútàẸbíFàájìÒfinỌ̀rọ̀-òkòwòÌnáwóÌṣèlúỌ̀rọ̀-àwùjọÈnìyànẸ̀kọ́ÌmòyeÌtòràwọ̀ÒfurufúỌ̀gbìnSáyẹ́nsì kọ̀mpútàFísíksìÌwòsànÀdánidáKẹ́místrìBàíọ́lọ́jìÁljẹ́bràÌtúwòÌṣíròÌṣedọ́gbaJẹ́ọ́mẹ́trìNọ́mbàTẹ̀ọ́rẹ́mùỌgbọ́nAyéAdágúnOrílẹ̀-èdèÒkunOrílẹ̀ÌlúÁfríkàÁsíàEuropeGúúsù Amẹ́ríkàÀríwá Amẹ́ríkàOgunOrílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀Ilẹ̀ọbalúayéỌ̀rọ̀-ayéijọ́unOlórí orílẹ̀-èdèOníṣọ̀nàÒṣeréOnímọ̀sáyẹ́nsìAmòyeOlóṣèlúOlùkọ̀wéOníṣòwòẸ̀sìn YorùbáÌmàleẸ̀sìn KrístìÌṣebúddhàÌṣehíndùÌmáralókunÌdárayáAmáralókunìtọ́jú ìleraÀrùnỌ̀rọ̀-àjàkálẹ̀àrùnDeutsch (jẹ́mánì)English (gẹ̀ẹ́sì)Français (faransé)Español (spánì)Italiano日本語 (japonês)Nederlands (neerlandês)Polski (polaco/polonês)Português (potogí)Русский (rọ́síà)العربية (árabe)Български (búlgaro)Català (catalão)한국어 (coreano)中文 (chinês)Dansk (dinamarquês)Slovencina (eslovaco)Slovenščina (esloveno)EsperantoSuomi (finlandês)עברית (hebraico)Magyar (húngaro)Bahasa Indonesia (indonésio)Lietuviu (lituano)Norsk (norueguês)فارسی (persa)Română (romeno)Српски / Srpski (sérvio)Svenska (sueco)Česká (tcheco/checo)Türkçe (turco)Українська (ucraniano)Tiếng Việt (vietnamita)Volapük (volapuque)Winaray












Ojúewé Àkọ́kọ́




Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́






Jump to navigation
Jump to search









Àdàkọ:ÀyọkàỌ̀sẹ̀ Àyọkà pàtàkì ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀



Àwòrán Ise-ona funfun Iboju Iyaoba Idia ilu Benin

Ẹ̀gbà ọrùn bí ìbòju tí Benin jẹ́ ẹ̀gbà ọrùn tí wọ́n gbẹ́ lére tí ó sì jẹ́ àwòrán akọni obìrin tí a mọ̀ si ìyá wa Olorì Idia ti ọ̀rundún mẹ́rìndínlógún ṣẹ́yìn. Ọmọ rẹ̀ Esigie tí ó jẹ́ ọba  ti Benin maa ń wọ́ èyí tí ó jọọ́ fún àwọn ọmọ ogun ẹ̀yìn ìya olorì. Ibojú yìyí tí ó jọrawọ méjì ní ó wà: Ìkan wà ní Ilé ọnà ti a mọ̀ sí British Museum ní ìlú London tí ìkejì sì wà ní ilé ọnà tí a mọ̀ sí Metropolitan Museum of Art in New York City.


Àwọn àpẹẹrẹ rẹ̀ lórí àkọ́lé kan náà wà ní Seattle Art Museum àti Linden Museum, tí ìkan ná sì wà ní ilé ibi tí wọ́n kò gba gbogboògbò láyè láti wọ̀, gbogbo rẹ̀ ní wọ́n kó nígbà ìwádí lọ sí ìlú Benin ti ọdún 1897.


Ìbojú yìí ti di àmì ìdánimọ̀ lóde òní ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríá̀ láti ìgbà ìpéjọpọ̀ kan tí a mọ̀ sí FESTAC 77 tí ó wáyé ní ọdún 1977.


Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ó ní ìrísí èyí tí ó jọ Ìbojú Ìbílẹ̀ Aláwọ̀dúdú, kíní kékeré tí gúngùn rẹ̀ kò ju 24cm lọ kìí ṣé fún wíwọ̀ sójú, Ọba lè wọ̀ọ́ sọ́rùn (tí ó sì maa bá mu) tàbí bi "ìlẹ̀kẹ̀ ìbàdí " (èyí tí ó sì maa bá ayẹyẹ tí ó fẹ́ sẹe mu). Èyí tí ó wà ní ilé ọnà Met àti èyí tí ó wà ní ilé ọnà British fẹ́ jọ ara wọn, méjèèjì ni ó jẹ́ àwòràn Olorì Idia
wearing ìlẹ̀kẹ̀ lórí, ìlẹ̀kẹ̀ lọ́rùn, ọgbẹ́ níwájú orí àti gbígbẹ́  èyí tí ó fàyè ọ̀nà méjì tí wọ́n lè fi ẹ̀gbà kọ́.


Lóde òní àwọn ènìyàn m,aa ń gbé onírú irú àworan tí ó jọ́ọ níbi ayẹyẹ láti lé ẹbọra búrúkú, ṣùgbọ́n ní bí ọrundún mẹ́rìndínlógún sẹ́yìn, wọ́n lè maa lòó fún ayẹyẹ ìya ọba. Ó dàbí wípé ní bí ìbẹ̀rẹ̀ ọrúndún mẹ́rìndínlógún sẹ́yìn ni wọ́n gbẹ́ àwọn ibojú méjèèjì, bóya ní ọdún 1520, nígbà tí Olorì Idia, ìyá ọba Oba Esigie, jẹ́ olùdájọ́ ní ilé ẹjọ́ ti Benin.
(ìtẹ̀síwájú...)






Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 30 Oṣù Kẹta Ní ọjọ́ òní...



Ọjọ́ 30 Oṣù Kẹta:


  • 1856 – Itowobowe Adehun Paris to fa opin si Ogun Krimea.

  • [[]]

Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...



  • 1962 – MC Hammer, American rap musician


  • 1964 – Tracy Chapman, American singer


  • 1976 – Obadele Thompson, Barbadian athlete

Àwọn aláìsí lóòní...



  • 1896 – Charilaos Trikoupis, seven times prime-minister of Greece (b. 1832)


  • 1949 – Friedrich Bergius, German chemist, Nobel Prize laureate (b. 1884)

Ọjọ́ míràn: 28 • 29 • 30 • 31 • 01 | ìyókù...








Nuvola apps filetypes.svgṢé ẹ mọ̀ pé...



Che Guevara



  • ... pé Ìlú New York kọ́kọ́ jẹ́ pípè bi New Amsterdam?

  • ... pé Guerrillero Heroico (aworan) tó jẹ́ àwòrán Che Guevara ni "fọ́tò tógbajùmọ̀ jùlọ láyé"?

  • ... pé àwọn tóún tẹ̀lé ẹ̀sìn Islam úngbàdúrà ní 5 lójúmọ́?

  • ... pé Mars dà bí pupa nítorí ìdóògún nínú àpáta rẹ̀ àti èruku lójúde rẹ̀?







Èbúté:Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìwòyí/Kókó orí Ìròyìn ìwòyí



Higgs, Peter (1929)3.jpg


  • Nelson Mandela ṣe aláìsí ní Johannesburg, Gúúsù Áfríkà.


  • Nobel fún Àlàfíà lọ sí Àgbájọ fún Ìdènà àwọn Ohun Ìjagun Ògùn Olóró.


  • Nobel fún Litiréṣọ̀ lọ sí Alice Munro.


  • Nobel fún Kẹ́místrì lọ sí Martin Karplus, Michael Levitt àti Arieh Warshel.


  • Nobel fún Físíksì lọ sí François Englert àti Peter Higgs (fọ́tò).


  • Nobel fún Ìwòsàn lọ sí James Rothman, Randy Schekman àti Thomas C. Südhof.






Ẹ tún wo ÌròyìnWiki ní èdè Gẹ̀ẹ́sì




Nuvola filesystems camera.pngÀwòrán ọjọ́ òní




Fogo, Cape Verde Islands.jpg

Fogo ní Cape Verde.








Wikimedia logo family complete.svg Àwọn Iṣẹ́-ọwọ́ Míràn



Wikimedia Foundation ni ó gba àlejò Wikipedia, egbe-alasepo ti ki se fun ere ti o tun se alejo opo awon ise-owo miran:












Wikiàyásọ

Wikiàyásọ
Àkójọ àwọn àmúsọ

Wikiatúmọ̀èdè

Wikiatúmọ̀èdè
Atúmọ̀èdè orísirísi èdè

Wikispecies

Wikispecies
Àkójọ àwọn irú ẹ̀dá

Wikiìròyìn

Wikinews
Ìròyìn ọ́fẹ̀










Wikisource

Wikisource
Àwọn àkọsíìwé ọ̀fẹ́

Commons

Wikimedia Commons
Àwòrán, ìró àti fídéò

Wikifásítì

Wikifásítì
Èlò ìkọ́ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́

Wikiìwé

Wikiìwé
Ìwéẹ̀kọ́ àti ìwéàwòṣe ọ̀fẹ́





Meta-Wiki

Meta-Wiki
Ibi àkóso ìṣẹ́-ọwọ́ Wikimedia

Wikidata

Wikidata
Ìbùdó ìmò ọ̀fẹ́




Àkíyèsí! — Àìṣojúṣájú · Ìlànà àyọkà kíkọ · Ẹ̀tọ́àwòkọ · Ìwà títọ́ · Ìṣeéyẹ̀wò · Ìlànà fún kíkọ lẹ́tà Yorùbá



Kíkọ àyọkà — Kíni Wikipedia jẹ́? · Àtúnṣe ojúewé · Àfikún àwòrán · Ìkópa · Tutorial · Àpótí ìdánwò



Ìrànwọ́ Wikipedia — Àwọn ojúewé tuntun · Àwọn àyọkà ọ̀wọ́n · Àwọn ojúewé fún ìyílédèdà · Àwọn àyọkà fún àtúnṣe · Ìṣọrẹ



Nípa Wikipédia — Abẹ́ igi · FAQ · Àwọn oníṣe Wikipedia · Àwọn alámùójútó · Wikimedia · Software · Àwọn statístíkì



Orúkọàyè — Wikipedia







Àdàkọ:GbogboẸ̀ka Àwọn èbúté àti ẹ̀ka àyọkà


























Àṣà

Lítíréṣọ̀ • Eré-ìdárayá • Fílmù • Orin • Tíátà • Ìṣeròyìn • Tẹlifísàn • Rédíò





Tẹknọ́lọ́jì

Iṣẹ́ẹ̀rọ • Internet • Àfigbébánisọ̀rọ̀ • Kọ̀mpútà





Àwùjọ

Ẹbí • Fàájì • Òfin • Ọ̀rọ̀-òkòwò • Ìnáwó • Ìṣèlú • Ọ̀rọ̀-àwùjọ • Ènìyàn • Ẹ̀kọ́ • Ìmòye





Sáyẹ́nsì

Ìtòràwọ̀ • Òfurufú • Ọ̀gbìn • Sáyẹ́nsì kọ̀mpútà • Físíksì • Ìwòsàn • Àdánidá • Kẹ́místrì • Bàíọ́lọ́jì





Mathimátíkì

Áljẹ́brà • Ìtúwò • Ìṣírò • Ìṣedọ́gba • Jẹ́ọ́mẹ́trì • Nọ́mbà • Tẹ̀ọ́rẹ́mù • Ọgbọ́n





Jẹ́ọ́gráfì

Ayé • Adágún • Orílẹ̀-èdè • Òkun • Orílẹ̀ • Ìlú • Áfríkà • Ásíà • Europe • Gúúsù Amẹ́ríkà • Àríwá Amẹ́ríkà





Ìtàn

Ogun • Orílẹ̀-èdè tẹ́lẹ̀ • Ilẹ̀ọbalúayé • Ọ̀rọ̀-ayéijọ́un





Ìgbésíayé

Olórí orílẹ̀-èdè • Oníṣọ̀nà • Òṣeré • Onímọ̀sáyẹ́nsì • Amòye • Olóṣèlú • Olùkọ̀wé • Oníṣòwò





Ẹ̀sìn àti ìgbàgbọ́

Ẹ̀sìn Yorùbá • Ìmàle • Ẹ̀sìn Krístì • Ìṣebúddhà • Ìṣehíndù





Ìlera

Ìmáralókun • Ìdárayá • Amáralókun • ìtọ́jú ìlera • Àrùn • Ọ̀rọ̀-àjàkálẹ̀àrùn






Àkọ́jọ kíkúnrẹ́rẹ́ · Ibiàkóso àwọn èdè Wikipedia · Ìdásílẹ̀ èdè Wikipedia tuntun









Jẹ́ kíkójáde láti "https://yo.wikipedia.org/w/index.php?title=Ojúewé_Àkọ́kọ́&oldid=523403"










Ètò ìtọ́sọ́nà



























(window.RLQ=window.RLQ||[]).push(function()mw.config.set("wgPageParseReport":"limitreport":"cputime":"0.140","walltime":"0.215","ppvisitednodes":"value":481,"limit":1000000,"ppgeneratednodes":"value":0,"limit":1500000,"postexpandincludesize":"value":30486,"limit":2097152,"templateargumentsize":"value":1477,"limit":2097152,"expansiondepth":"value":12,"limit":40,"expensivefunctioncount":"value":1,"limit":500,"unstrip-depth":"value":0,"limit":20,"unstrip-size":"value":1,"limit":5000000,"entityaccesscount":"value":0,"limit":400,"timingprofile":["100.00% 68.710 1 -total"," 25.07% 17.223 1 Àdàkọ:Pp-vandalism"," 19.58% 13.453 1 Àdàkọ:Pp-meta"," 13.52% 9.288 1 Àdàkọ:ÀwòránỌjọ́Òní"," 12.91% 8.868 1 Wikipedia:Ojúewé_Àkọ́kọ́/Àyọkà_Ọ̀sẹ̀/Ọ̀ṣẹ̀_yí"," 9.84% 6.761 1 Àdàkọ:Aworan"," 9.37% 6.437 1 Àdàkọ:ÀyọkàỌ̀sẹ̀"," 8.30% 5.701 1 Wikipedia:Àwọn_Ìṣẹ̀lẹ̀_Bíi_Ọjọ́_Òní/Ọjọ́_30_Oṣù_Kẹta"," 7.43% 5.103 1 Wikipedia:Ṣé_ẹ_mọ̀_pé..."," 6.67% 4.584 1 Àdàkọ:WikipediaLang2"],"cachereport":"origin":"mw1257","timestamp":"20190330204121","ttl":3600,"transientcontent":true);mw.config.set("wgBackendResponseTime":132,"wgHostname":"mw1266"););

Popular posts from this blog

Tamil (spriik) Luke uk diar | Nawigatjuun

Align equal signs while including text over equalitiesAMS align: left aligned text/math plus multicolumn alignmentMultiple alignmentsAligning equations in multiple placesNumbering and aligning an equation with multiple columnsHow to align one equation with another multline equationUsing \ in environments inside the begintabularxNumber equations and preserving alignment of equal signsHow can I align equations to the left and to the right?Double equation alignment problem within align enviromentAligned within align: Why are they right-aligned?

Training a classifier when some of the features are unknownWhy does Gradient Boosting regression predict negative values when there are no negative y-values in my training set?How to improve an existing (trained) classifier?What is effect when I set up some self defined predisctor variables?Why Matlab neural network classification returns decimal values on prediction dataset?Fitting and transforming text data in training, testing, and validation setsHow to quantify the performance of the classifier (multi-class SVM) using the test data?How do I control for some patients providing multiple samples in my training data?Training and Test setTraining a convolutional neural network for image denoising in MatlabShouldn't an autoencoder with #(neurons in hidden layer) = #(neurons in input layer) be “perfect”?